ORÍ KÌÍNÍ
ÌPILÊ?Ê I?Ë ÌWÁDÌÍ
1.0 ÌFÁÀRÀ
Kò sí àníàní pé ìlò èdè ?e pàtàkì nínú i?ë ônà aláwòmö lítíré?õ. Tí a bá sô pé i?ë ônà lítíré?õ kan dùn, èdè inú rê ló dùn. a wá le sô pé améwìdùn, amútàndùn ni èdè, amáyédùn sì ni pêlú. Fún ìdí èyí, kì í ?e àìrí-nýkan-?e bí a bá sô pé a fë ?àyêwò ìlò èdè inú i?ë lítíré?õ kan.
Ohun to jç wá lógún nínú i?ë ìwádìí yìí ni láti ?e àyêwò fínnífínni, õnà tí Olúyëmisí Adébõwálé gbà lo èdè nínú ewì Ìgbà Lonígbàákà. Èyí ni yóò ràn wá löwö láti ?e ìgbéléwõn ààyè òýkõwé náà láàrín àwôn òýkõwé ewì alákôsílê Yorùbá yòókù. Bákan náà, a ò le sô ipa tí i?ë òýkõwé náà le kó nínú ìdàgbàsókè ewì àpilêkô Yorùbá ní pàtàkì àti àwùjô Yorùbá lápapõ.
1.1 ÈRÈDÍ I?Ë ÌWÁDÌÍ
Yorùbá bõ wön ní êsê kan kì í dédé ?e. Bí a ?e mõ pé kò sí ènìyàn kan tí yóò dáwö lé i?ë kan tí kò ní ní ìdí kan pàtó tí ó fi ?i?ë náà. Onírúurú nýkan ló mú wa lökàn tí a fi ?i?ë àpilêkô yìí.
Lákõökö a ti ní ìmõ lö lökàn-ò-jõkan lórí bí a ?e le ?e ìtúpalê i?ë aláwòmö lítíré?õ kan. Fún ìdí èyí, a ní láti ?àmúlò ìmõ náà nítorí pé nýkan tí a bá mõ tí a kò lò bí i pé a kò mõ ön ni.
Bákan náà ni a ?e i?ë yìí láti fa onírúurú àkíyèsí yô yálà àléébù tàbí ìwúlò lórí ìwé Ìgbà Lonígbàákà tí i?ë yìí dálé àwôn àkíyèsí wõnyìí yóò wúlò fún wa àti fún àwùjô lápapõ. Yàtõ sí èyí, nýkan mìíràn tó tún mú wa dáwölë i?ë ìwádìí yìí ni pé ìwé Ìgbà Lonígbàákà jë ìwé tuntun láwùjô, kò sí tí ì sí çnikëni tó ti ?e i?ë ìtúpalê ìwé náà bí i ti àwôn ìwé yókù tó jë pé ojojúmö ni àwôn onímõ lölökan-ò-jõkan ? ?i?ë lé wôn lórí. A wòye pé ó ye kí omi tuntun rú kí çja tuntun sí wôbê. Èyí yóò mú kí a le ?àmúlò ìmõ wa nípa ìtúpalê i?ë aláwòmö lítíré?õ fínnífínní lai jë pé a wo nýkan tí àwôn onímõ ti ?e lórí i?ë náà. Ìdí mìíràn tí a fi ?i?ë yìí ni pé òýkõwé jë obìnrin i?ë yìí yóò mú kí i?ë àwôn obìnrin náà bêrê sí ní di ìlú mõöká.
1.2 ÀÝFÀÀNÍ I?Ë ÌWÁDÌÍ
Lákõökö i?ë yìí yóò là wá lóye yóò sí tún fún wa ní ìmõ kún ìmõ nítorí ôgbön kò pín sí ibìkan bí a bá ?e ? wádìí nýkan náà ni ìmõ wa yóò máa gbòró sí nítorí ôgbön kò pín síbí kan. Yàtõ sí èyí i?ë yìí yóò mú ìmõ êkö têsíwàjú nítorí pé àwôn òýkõwé ti ?i?ë gbënàgbënà, tiwa ni láti ?i?ë gbënugbënu. Èyí yóò ran àwôn òýkõwé àti a?àtúpalê löwö láti ni ìmõ kún ìmõ.
Èyí nìkan kö, i?ë yìí yóò fún wa ni àýfààní láti ní ìrírí lólökan ò jõkan. Èyí le wáyé yálà nígbà tí a ? ?e ìwádìí lórí i?ë yìí tàbí ìgbà tí a ?e àkójôpõ i?ë yìí. Gëgë bí a ?e mõ pé lítíré?õ máa ? ?àfihàn ìgbé ayé àwùjô kan ni pàápàá jùlô ì?êlê àwùjô ni ó máa ? jçyô jù nínú lítíré?õ. I?ë yìí yóò ran àwôn ènìyàn löwö láti mõ nípa àwùjô Yorùbá. A ó wò ó bóyá àyípadà ti dé bá àwùjô náà, bóyá àyípadà rere ni tàbí búburu.
Bákan náà, i?ë yìí yóò fún òýkõwé ní àýfààní láti di ìlú mõká nítorí pé bí i?ë bá ?e ? lô lórí ìwé òýkõwé kan ni òýkõwé bëê yóò máa di gbajúmõ láwùjô. Tí a bá wo àwôn òýkõwé tó gbajú gbajà láwùjô Yorùbá, a ó rí i pé i?ë ti àwôn onímõ ? ?e lórí i?ë wôn ló jë kó rí bëê.
Síwájú sí i, i?ë yìí yóò mú kí ìwé Ìgbà Lonígbàákà dé ojú táyé, èyí pàápàá á fún wa ni ààyè láti le töka sí ibi tí àléébù bá wa nínú ìwé náà èyí yóò mú kí òýkõwé le ?e àtún?e tó báyç láti mú kí i?ë mìíràn dára. Bí a bá wò ó, a ó rí i pé obìnrin ni òýkõwé ìwé yìí. I?ë yìí yóò fún àwôn obìnrin bí i tirê ní ìrírí láti le fë dàbí rê nítorí kò sí òýkõwé tí kò fë di gbajú gbajà láwùjô. Yàtõ sí èyí i?ë yìí yóò ran èdè Yorùbá löwö nítorí pé àwôn ènìyàn yóò bêrê sí ní fi ojú ire wo Yorùbá àti láti nífç sí èdè Yorùbá.
Ní àkótán, i?ë yìí le dúró gëgë bí àtçgùn fún àwôn tí ó ? bõ lëyìn tí ó fë ?e ìwádìí lórí irú i?ë yìí.
1.3 ÔGBÖN ÌWÁDÌÍ
Õpõlôpõ onímõ ló ti sõrõ nípa ?í?e ìwádìí lára wôn ni Abímbölá (1995) ó pe ìwádìí ní
“Knowledge seeking that assists in adding more information to an existing compartment or content of knowledge or investigation with the soul aim of getting more knowledge, preferably new knowledge”.
Ìwádìí ?í?e tí ó ?e ìrànwö fún ìfikún ìmõ tàbí ìwádìí pêlú ìmõlára àti wá ìmõ kún ìmõ, pàápàá jùlô ìmõ tuntun.
Ohun tí Abímbölá ? gbìyànjú láti sô ni pé ìwádìí ni lílo ôgbön inú àti òye ikùn láti mú ohun titun jáde nípa ìmõ kan.
Onyene àti Anunnu (2000) pe ìwádìí ní:
a process of finding out solutions or answers to problems. It is also a planning process towards seeking and getting desirable information leading to providing plausible anwer(s) to reasonable questions to enable people forecast future happenings and carry out structured investigation to solve problems.
Ìwádìí ni õnà tí à ? gbà wá õnà àbáyô tàbí ìdáhùn sí ì?òro. Òun náà ni ìlànà tí a gbé kalê fún wíwa àti rírí àwôn tí a fë tí yóò sí ?okùnfà ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè tó mögbön wá èyí yóò mú kí àwôn èèyàn le fojú inú wo àwôn ì?êlê ôjö iwájú tí wôn yóò sí ?e ìwádìí tó ní ètò láti dëkun ì?òro.
Ohun tí àwôn onímõ yìí ? sô ni pé ìwádìí jë ohun tí çnìkan dáwölé tó yôrí tó sí wúlò fún ìtêsíwájú ìmõ àti fún àwùjô lápapõ. Ó jë àfikún ìmõ àti mímú ìmõ têsíwàjú bí ìwádìí tí çnìkan ?e kò bá le fi kún ìmõ tó ti wà nílê tëlê, i?ë jabutç ni olùwádìí bëê ?e.
Yorùbá bõ wön ní ìgbà kan ò lo ilé ayé gbó, ìgbà kan ? lô, ìgbà kan ? bõ. Ní ìgbà báyému tí a wà yìí, orí?irí?i ôgbön ni a le ta láti ?e ìwádìí kan tàbí òmíràn. Lára wôn ni; ìfõrõ-wáni – lënu-wò láti lô inú ôgbön ìwádìí yìí, a ni láti lô àwôn tí à ? wádìí wôn tàbí i?ë wôn lô láti fi õrõ wá wôn lënu wò nítorí Yorùbá bõ wön ni çnu oníkàn la tí ? gbö põn ún. A ?e èyí láti fìdí òótö múlê nípa nýkan tí a fë mõ yálà nípa òýkõwé ni tàbí nípa ìwé tí ó kô. A le ?e èyí nípa lílo ìlànà ìbéèrè àti ìdáhùn. A máa ? ?ábà gba ohùn sílê nígbà tí a bá ? ?e ìfõrõ-wáni-lënu-wò. A ti gbôdõ ?ètò àwôn ìbéèrè wõnyìí sílê kí a tó tô òýkõwé fún ra rê lô láti wá ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè wa.
Síwájú sí i, a rí ôgbön ìwádìí lílo àtç tàbí àtòjô ìbéèrè (Questionaire format) èyí máa ? kún fún orí?ìírí?ìí ìbéèrè tí ó le ran olùwádìí löwö nínú i?ë ìwádìí rê. A le pín ìwé ìbéèrè náà fún àwôn akëkõö, àwôn olùkö àwôn ò?ì?ë ôba àti bëê bëê lô. Ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè náà le jë bëê ni tàbí bëê kô, ó sí le jë gbólóhùn ?ókí. Àýfààní tó wà nínú ôgbön ìwádìí yìí ni pé ó máa ? fún olùwádìí ní àýfààní láti gba õkan-ò-jõkan ìmõ jô lórí ohun tí ó ? wádìí lé lórí, nítorí bí õrõ náà bá ?e rí sí àwôn abënà-ìmõ ni wôn yóò ?e dáhùn àwôn ìbéèrè tí wön bá bi wön. Ìdáhùn wôn ni yóò jë kí a mô ìhà tí wön kô sí àwôn ìbéèrè náà.
Ôgbön ìwádìí yìí kò ?àì ní àléébù tirê nípa pé ó máa ? gba õpõ owó löwö olùwádìí. Èyí nìkan kö, olùwádìí le má rí àwôn àtç ìbéèrè tí ó ti pín gbà padà tán lëêkan náà tàbí kí ó má tilê rí òmíràn gbà rárá.
Ôgbön ìwádìí mìíràn tún ni èyí tí a mõ sí à?àkíyèsí akópa èyí tí ó túmõ sí pé olùwádìí yóò bá wôn kópa nínú ohun tí i ? wádìí lé lórí nípa ?í?e èyí, olùwádìí yóò mô àwôn nýkan mìíràn tí ó le mõ tí ó bá ?e ìfõrõ-wáni-lënu-wò lödõ àwôn abënà-ìmõ rê. ?ùgbön ôgbön ìwádìí yìí le má yôrí sí rere tí àwôn abënà-ìmõ bá mõ pé ó wá ?e ìwádìí ni kì í ?e pé olùwádìí wá kópa lóòótö.
Ôgbön ìwádìí mìíràn ni ìwòran à?àkíyèsí. Èyí ni kí olùwádìí ó ?e àmúlò èrò ìgbohùn sílê tàbí fídíò láti ká àwôn ì?êlê tí ó sílê bí wön ?e ? ?çlê.
Olùwádìí tún le lô sí àwôn yàrá ìkówe sí lökàn-ò-jõkan láti wá ìmõ kún ìmõ àti fún ìtösönà. Ní àkótán, ôgbön ìwádìí mìíràn ni gbígba ìmõ lórí èrò amáyélu-jára (Internet) nítorí õpõlôpõ ìmõ ni êyán le rí gbà lórí èrò náà.
Ní ti àpilêkô yìí a lo ôgbön ìwádìí ìfõrõ-wáni-lënu-wò a sì têlé ìlànà títô àwôn tí à ? wádìí i?ë wôn lô láti fí õrõ wá wôn lënu wò nítorí Yorùbá bõ wön ní çnu oníkàn là á ti ? gbö põn-ún. ?í?e èyí yóò fún wa ní àýfààní láti ni ìmõ kún ìmõ lórí i?ë yìí. A ?e èyí láti fi ìdí òótö múlê nípa nýkan tí a fë mõ yálà nípa òýkõwé ni tàbí nípa ìwé tí ó kô. A ?e èyí nípa lílo ìlànà ìbéèrè àti ìdáhùn. Àwôn ìbéèrè yìí ni mo ti ?ètò kí ? tó tô òýkõwé lô láti wá ìdáhùn sí àwôn ìbéèrè náà. Bákan náà mo gba ohùn sílê nígbà tí mò ? ?e ìfõrõ-wáni-lënu-wò náà.
Bákan náà ni a tún lô sí yàrá ìkówésí lökan-ò-jõkan láti wá ìmõ kún ìmõ àti fún ìtösönà. Ôgbön mìíràn tí a tún lò fún i?ë ìwádìí yìí ni gbígba ìmõ lórí êrô amáyélu-jára. Ôgbön yìí wúlò púpõ fún i?ë yìí nítorí ó mú kí ìmõ olùwádìí gbòòrò sí, ó jë kí òótö àbájáde ìwádìí náà túbõ fçsê múlê sí i.
1.4 ÀÀLÀ I?Ë ÌWÁDÌÍ
Àwôn ewì õjõgbön Olúyëmisí Adébõwále ni i?ë yìí dálé àwôn nýkan tí a sì gbé yêwò ni ônà tó gbà lo èdè tó fi mú kí i?ë rê yàtõ sí ìlò èdè ojojúmö. Bákan náà a lo tíörì ì?ôwö-lo-èdè láti fi èyí hàn. a mënu ba àwôn tíörì mìíràn ní ?ókí. I?ë yìí kò ju ìlò èdè lô àti sítàì òýkõwé tó fi gbé àwôn ìlò èdè náà jáde.
1.5 ÈTÒ ÌWÁDÌÍ
I?ë ìwádìí tí kò bá ní ètò kì í ?e èyí tó dára nítorí pé kò ni jë kí i?ë ìwádìí bëê múnádóko tó bí ó ?e yç.
Orí mërin ni i?ë yìí ni. Èyí rí bëê nítorí pé a kò fë kí i?ë náà ó ?ùpõ sí ojú kan kí àwôn kókó tí a fë fà yô má baà forí mú sínú orí kan ?o?o.
Orí kìíní i?ë yìí dá lórí ìpilê?ê ìwádìí níbi tí a ti ?àlàyé èrèdí i?ë àpilêkô yìí. Síwájú sí i a tún fçnuba ôgbön ìwádìí èyí tó jë õnà tí a gbà láti kó àwôn èròjà ìwádìí wa jô bëê gëgë ni a mënu ba àwôn àýfààní tí ó wà nínú i?ë ìwádìí èyí sí ni a fi àkòrí ìwúlò ìwádìí sí. Ètò ìwádìí lo gbêyìn orí kìíní.
Ní orí kejì, a ?e àgbéyêwò i?ë àwôn asíwájú èyí tí àkóónú rê dá lórí lítíré?õ Yorùbá lápapõ. A tún ?àlàyé nípa tíörì ì?àmúlò èyí tí ?e tíörì ì?ôwö-lo-èdè.
Orí këta gan ni êmí i?ë yìí nítorí pé ibè gan ni a ti ?àlàyé kíkún lórí ì?ôwö-lo-èdè òýkõwé ìyçn onírúurú sítàì tó wà nínú i?ë rê. Bákan náà ni a sõrõ nípa àwôn çní tí a ?i?ë le lórí ní ?ókí. A sí tún sõrõ nípa Olúyçmisí Adébõwálé gëgë bí i òýkõwé àti akéwì Yorùbá.
Ní orí kërin tó gbêyìn i?ë àpilêkô yìí ni a ti ?e lámèyítö lórí i?ë yìí. a fçnuba àmúyç àti àléébù i?ë yìí. Bákan náà ni a tún sô àríwísí tiwa lórí i?ë ìwádìí yìí.
Lëyìn èyí ni àgbálôgbábõ, èyí ni ìgúnlê pêlú ìmõràn fún àwôn a?èwádìí tó ? bõ lëyìn. Níparí a ?e àkójôpõ orúkô àwôn ìwé tó ràn wá löwö fún i?ë ìwádìí yìí.
Accounting/ Audit/ Finance Jobs
Administration/ Office/ Operations Jobs
Advertising/ Social Media Jobs